Search This Blog

Thursday, 4 January 2018

LYRICS: OLA - ATOBIJU FEATURING ADEYINKA ALASEYORI


Chorus -2x
Olorun wa,
Ayeraye mo gbe o ga o
Mimo mimo Atobiju
Eyin nikan l'ogo ola ye fun
Verse 1 - Ola
From the rising of the sun
Unto it's going down
Mi o r'eni to jo o
Ti mole fi o we
Ologo ara nla, t'oni gbogbo ogo
Ashiwere wipe, Olorun k'osi
N'oje ba won so, Nitori moti mo o
Olola Ni JESU mi, ewa re k'oja oye
Baba o ni bebe, sa ma t'oju mi lo
Olorun Baba Agba Oye.
Chorus -2x
Olorun wa,
Ayeraye mo gbe o ga o
Mimo mimo Atobiju
Eyin nikan l'ogo ola ye fun
Adeyinka o ya now
Verse 2 - Adeyinka Alaseyori
Iyin re o le dawo duro, lenu MI Oluwa
Iba re Akoda Aye, Aseda l'ode orun
Asaju Ogun la lo, Akehin Ogun l'oje
Paripari Ola, Alebe ilu a sasi
O da wa si,
O pa wa mo
Olore e e e
Iwonikan l'awa gbe ga
Iwonikan l'awa pe bo
From the beginning of our lives
Till this very moment
Eh Eh Eh, You've been faithful
Ever faithful God
Chorus -1x
Olorun wa,
Ayeraye mo gbe o ga o
Mimo mimo Atobiju
Eyin nikan l'ogo ola ye fun
Drums Interlude
Bridge
Call: E ba n'kira, E ba n'kira, E ba n'kira fun
Response: E ba n'kira 3x
Olori Aye gbogbo - E ba n'kira fun
T'omu riri jade ninu airi - E ba n'kira fun
Orisun Ayomi l'oje - E ba n'kira fun
O ni ole ojo merin dide Baba - E ba n'kira fun
O mu omi jade lati inu apata - E ba  n'kira fun
O rin Lori omi, sibe ko ri - E ba n'kira fun
Ake to bo sinu omi, igi lofi gbe jade - E ba n'kira fun
JESU Olugbala o wo odi Jericho - E ba n'kira fun
Talaka wa Lo jeun pelu awon Oba  - E ba n'kira fun
Ari na Ari Lo wa di ohun igbagbe - E ba n'kira fun
Agan ojo pipe, won di Iya olomo - E ba n'kira fun
K'osi ohun to s'oro se fun Olorun Bami - E ba n'kira fun
Ah Ah ATOBIJU
E ba n'kira fun.
Download song via this link  http://onabajoolawale.com/discography/atobiju/#.Wjj55pko_qA
Fast Download Link https://my.notjustok.com/track/download/id/298501
--------------------------------------
FOLLOW OLA 
www.onabajoolawale.com
www.facebook.com/onabajoolawale
www.instagram.com/onabajoolawale
www.twitter.com/onabajoolawale
www.onabajoolawale.blogspot.com
www.youtube.com/olawaleonabajo
For Booking, call  08090173955
--------------------------------------
@SPLENDOURMUSIC

No comments:

Post a Comment